Psalms 78:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọmọ eniyan jẹ lára oúnjẹ àwọn angẹli; Ọlọrun fún wọn ní oúnjẹ àjẹtẹ́rùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Enia jẹ onjẹ awọn angeli; o rán onjẹ si wọn li ajẹyo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn jẹ oúnjẹ àwọn ańgẹ́lì; o fún wọn ní oúnjẹ ní àjẹyó