Psalms 78:29 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn eniyan náà jẹ, wọ́n sì yó; nítorí pé Ọlọrun fún wọn ní ohun tí ọkàn wọn fẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni nwọn jẹ, nwọn si yo jọjọ: nitoriti o fi ifẹ wọn fun wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn jẹ, wọ́n sí yó jọjọ nítorí ó ti fún wọn ní ohun tí wọn fìtara bẹ̀bẹ̀ fún