Psalms 78:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọlọrun bínú sí wọn; ó pa àwọn tí ó lágbára jùlọ ninu wọn, ó sì lu àṣàyàn àwọn ọdọmọkunrin Israẹli pa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibinu Ọlọrun de si ori wọn, o pa awọn ti o sanra ninu wọn, o si lù awọn ọdọmọkunrin Israeli bolẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbínú Ọlọ́run dìde sí wọn ó pa àwọn tí ó jùlọ nínú wọn, ó sì lu àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin Ísírẹ́lì bolẹ̀.