Psalms 78:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Sibẹsibẹ wọ́n tún dẹ́ṣẹ̀; pẹlu gbogbo iṣẹ́ ìyanu rẹ̀, wọn kò gbàgbọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu gbogbo wọnyi nwọn nṣẹ̀ siwaju, nwọn kò si gbà iṣẹ iyanu rẹ̀ gbọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú gbogbo ìwọ̀nyí, wọn ń sá síwájú; nínú gbogbo iṣẹ́ ìyanu Rẹ̀, wọ́n kò gbàgbọ́