Psalms 78:36 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn wọn kàn ń fi ẹnu wọn pọ́n ọn ni; irọ́ ni wọ́n sì ń pa fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ẹnu wọn ni nwọn fi pọ́n ọ, nwọn si fi ahọn wọn ṣeke si i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n nígbà náà ni wọ́n yóò pọ́n-ọn pẹ̀lú ẹnu wọ́n wọ́n fí ahọ́n wọ́n purọ́ fún un;