Psalms 78:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Sibẹ, nítorí pé aláàánú ni, ó dárí ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n, kò sì pa wọ́n run; ní ọ̀pọ̀ ìgbà ni ó dáwọ́ ibinu rẹ̀ dúró, tí kò sì fi gbogbo ara bínú sí wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn on, o kún fun iyọ́nu, o fi ẹ̀ṣẹ wọn jì wọn, kò si run wọn: nitõtọ, nigba pupọ̀ li o yi ibinu rẹ̀ pada, ti kò si ru gbogbo ibinu rẹ̀ soke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣíbẹ̀ ó ṣàánú; ó dárí àìṣedédé wọn jìn òun kò sì pa wọn run nígbà kí ì gbà ló ń dá ìbínú Rẹ̀ dúró kò sì rú ìbínú Rẹ̀ sókè