Psalms 78:40 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìgbà mélòó ni wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i ninu ijù, tí wọ́n sì bà á lọ́kàn jẹ́ ninu aṣálẹ̀!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Igba melo-melo ni nwọn sọ̀tẹ si i li aginju, ti nwọn si bà a ninu jẹ ninu aṣálẹ!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà gbogbo ní wọn ń ṣọ̀tẹ̀ síi ní ihà wọn mú-un bínú nínú ilẹ̀ tí ó di ahoro!