Psalms 78:46 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó mú kí kòkòrò jẹ èso ilẹ̀ wọn; eṣú sì jẹ ohun ọ̀gbìn wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O fi eso ilẹ wọn fun kokoro pẹlu, ati iṣẹ wọn fun ẽṣú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fi ọkà wọn fún láńtata àwọn irè oko wọn fún eṣú