Psalms 78:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó fi ìlànà lélẹ̀ fún ìdílé Jakọbu; ó gbé òfin kalẹ̀ fún àwọn ọmọ Israẹli. Ó pa á láṣẹ fún àwọn baba ńlá wa, pé kí wọ́n fi kọ́ àwọn ọmọ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti o gbé ẹri kalẹ ni Jakobu, o si sọ ofin kan ni Israeli, ti o ti pa li aṣẹ fun awọn baba wa pe, ki nwọn ki o le sọ wọn di mimọ̀ fun awọn ọmọ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó gbé ẹ̀rí kalẹ̀ ní Jákọ́bù o sì fìdí àṣẹ múlẹ̀ ní Ísírẹ́lì, èyí tí ó páláṣẹ fún àwọn baba ńlá wa láti kọ́ àwọn ọmọ wọn,