Psalms 78:51 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
O kọlu gbogbo àkọ́bí wọn ní ilẹ̀ Ijipti, àní, gbogbo àrẹ̀mọ ninu àgọ́ àwọn ọmọ Hamu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si kọlu gbogbo awọn akọbi ni Egipti, olori agbara wọn ninu agọ Hamu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó kọlu àwọn àkọ́bí ọmọ ọkùnrin Éjíbítì Olórí agbára wọn nínú àgọ́ Ámù