Psalms 78:52 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, ó kó àwọn eniyan rẹ̀ jáde bí agbo ẹran ó sì dà wọ́n láàrin aṣálẹ̀ bí agbo aguntan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn o mu awọn enia tirẹ̀ lọ bi agutan, o si ṣe itọju wọn ni iju bi agbo-ẹran.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ó mú àwọn ènìyàn Rẹ̀ jáde bí ọ̀wọ́ ẹran; ó sọ́ wọn gẹ́gẹ́ bí àgùntàn nínú ihà.