Psalms 78:53 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó dà wọ́n lọ láìléwu, ẹ̀rù kò bà wọ́n; òkun sì bo àwọn ọ̀tá wọn mọ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe amọna wọn li alafia, bẹ̃ni nwọn kò si bẹ̀ru: ṣugbọn okun bò awọn ọta wọn mọlẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó dáàbòbò wọ́n dáadáa, nítorí náà ni ẹ̀rù kò ṣe bà wọ́n ṣùgbọ́n òkun padé mọ́ àwọn ọ̀tá wọn.