Psalms 78:57 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n yipada, wọ́n sì hu ìwà ọ̀dàlẹ̀ bíi ti àwọn baba ńlá wọn; wọn kò ṣe é gbẹ́kẹ̀lé, wọ́n dàbí ọfà tí ó tẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nwọn yipada, nwọn ṣe alaiṣotitọ bi awọn baba wọn: nwọn si pẹhinda si apakan bi ọrun ẹ̀tan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gẹ́gẹ́ bí baba wọn, wọn jẹ́ aláìsòdodo gẹ́gẹ́ bi ọrun ẹ̀tàn