Psalms 78:58 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n fi ojúbọ àwọn oriṣa wọn bí i ninu; wọ́n sì fi ère wọn mú un jowú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti nwọn fi ibi giga wọn bi i ninu, nwọn si fi ere finfin wọn mu u jowu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n bí nínú pẹ̀lú ibi gíga wọn; wọn rú owú Rẹ̀ sókè nípa òrìṣà wọn