Psalms 78:60 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó kọ ibùgbé rẹ̀ ní Ṣilo sílẹ̀, àní, àgọ́ rẹ̀ láàrin ọmọ eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li o kọ̀ agọ Ṣilo silẹ, agọ ti o pa ninu awọn enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó kọ àgọ́ Ṣílò sílẹ̀, àgọ́ tí ó ti gbé kalẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn.