Psalms 78:65 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, OLUWA dìde bí ẹni tají lójú oorun, bí ọkunrin alágbára tí ó mu ọtí yó tí ó ń kígbe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana li Oluwa ji bi ẹnipe loju orun, ati bi alagbara ti o nkọ nitori ọti-waini.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA sì jí gẹ́gẹ́ bí ẹni ojú oorun, gẹ́gẹ́ bí ọkùnrin ti i jù kúrò nínú ìraníyè ọtí.