Psalms 78:67 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó kọ àgọ́ àwọn ọmọ Josẹfu sílẹ̀; kò sì yan ẹ̀yà Efuraimu;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu o kọ̀ agọ Josefu, kò si yàn ẹ̀ya Efraimu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ó kọ́ àgọ́ Jósẹ́fù, kò sì yan ẹ̀yà Éfúráímù;