Psalms 78:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Efuraimu kó ọrun, wọ́n kó ọfà, ṣugbọn wọ́n pẹ̀yìndà lọ́jọ́ ìjà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Efraimu ti o hamọra ogun, ti nwọn mu ọrun, nwọn yipada li ọjọ ogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọkùnrin Éfúráímù, tí ó há mọ́ ọ tí wọ́n mú ọrun, wọ́n yípadà ní ọjọ́ ogun