Psalms 79:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọlọrun, àwọn orílẹ̀-èdè abọ̀rìṣà ti wọ inú ilẹ̀ ìní rẹ; wọ́n ti ba ilé mímọ́ rẹ jẹ́; wọ́n sì ti sọ Jerusalẹmu di ahoro.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ỌLỌRUN, awọn keferi wá si ilẹ-ini rẹ; tempili mimọ́ rẹ ni nwọn sọ di ẽri; nwọn sọ Jerusalemu di òkiti-alapa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run àwọn orílẹ̀ èdè ti wà ilẹ̀ ìní Rẹ; wọn ti bá tẹ́ḿpìlì mímọ́ Rẹ jẹ́, wọn di Jérúsálẹ́mù kù sí òkìtì àlàpà.