Psalms 79:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí ló dé tí àwọn orílẹ̀-èdè yóo fi máa sọ pé, “Níbo ni Ọlọrun wọn wà?” Níṣojú wa, gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn iranṣẹ rẹ tí a pa lára àwọn orílẹ̀-èdè!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori kili awọn keferi yio ṣe wipe, Nibo li Ọlọrun wọn wà? jẹ ki a mọ̀ igbẹsan ẹ̀jẹ awọn iranṣẹ rẹ ti a ta silẹ loju wa ninu awọn keferi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn orílẹ̀ èdè yóò sì máa wí pé, “Níbo ni Ọlọ́run wọn wà?” ní ojú wa. Kí a mọ̀ láàrin àwọn orílẹ̀ èdè kí ó sì gbẹ̀san àwọn ẹ̀jẹ̀ ìránṣẹ́ Rẹ̀ tí a tú jáde.