Psalms 79:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA, san ẹ̀san ẹ̀gàn tí àwọn aládùúgbò wa gàn ọ́, san án fún wọn ní ìlọ́po meje,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki o si san ẹ̀gan wọn nigba meje fun awọn aladugbo wa li aiya wọn, nipa eyiti nwọn ngàn ọ, Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
San án padà sí àyà àwọn aládùúgbò wa nígbà méje nípa ẹ́gàn tí wọn tí gàn ọ́ OLÚWA.