Psalms 79:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Tú ibinu rẹ sórí àwọn orílẹ̀-èdè tí kò mọ̀ ọ́, ati orí àwọn ìjọba tí kò sìn ọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dà ibinu rẹ si ori awọn keferi ti kò mọ̀ ọ, ati si ori awọn ijọba ti kò kepè orukọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tú ìbínú Rẹ̀ jáde sí orílẹ̀-èdè tí kò ní ìmọ̀ Rẹ, lórí àwọn ìjọba tí kò pe orúkọ Rẹ;