Psalms 8:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA, Oluwa wa, orúkọ rẹ níyìn pupọ ní gbogbo ayé! Ìwọ ni o gbé ògo rẹ kalẹ̀ lókè ọ̀run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA, Oluwa wa, orukọ rẹ ti ni iyìn to ni gbogbo aiye! iwọ ti o gbé ogo rẹ kà ori awọn ọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA, OLÚWA wa, orúkọ Rẹ̀ ti tó tóbi tó ní gbogbo àyé! Ìwọ ti gbé ògo Rẹ̀ ga ju àwọn ọ̀run lọ.