Psalms 80:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jọ̀wọ́ tún yipada, Ọlọrun àwọn ọmọ ogun! Bojúwolẹ̀ láti ọ̀run, kí o sì wò ó; kí o sì tọ́jú ìtàkùn àjàrà yìí,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yipada, awa mbẹ ọ, Ọlọrun awọn ọmọ-ogun: wolẹ lati ọrun wá, ki o si wò o, ki o si bẹ àjara yi wò:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yípadà sí wa, àwa ń bẹ̀ ọ, Ọlọ́run! Bo jú wolẹ̀ láti ọ̀run kí o sì wò ó! Kí o sì bẹ àjàrà yìí wò,