Psalms 80:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
O mú ìtàkùn àjàrà kan jáde láti Ijipti; o lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde, o sì gbìn ín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti mu ajara kan jade ti Egipti wá: iwọ ti tì awọn keferi jade, iwọ si gbin i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ mú àjàrà jáde láti Éjíbítì; ìwọ lé àwọn aláìkọlà jáde, o sì gbìn-ín.