Psalms 81:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà mo fi wọ́n sílẹ̀ sinu agídí ọkàn wọn, kí wọn máa ṣe ohun tó wù wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni mo fi wọn silẹ fun lile aiya wọn: nwọn si nrìn ninu ero ara wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ni mo ṣe fi wọ́n fún ọkàn líle wọn láti máa rìn ní ọ̀nà ẹ̀tàn wọn.