Psalms 81:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé àṣẹ ni, fún àwọn ọmọ Israẹli, ìlànà sì ni, láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun Jakọbu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori eyi li aṣẹ fun Israeli, ati ofin Ọlọrun Jakobu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni àṣẹ fún Ísírẹ́lì, àti òfin Ọlọ́run Jákọ́bù.