Psalms 81:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó pa á láṣẹ fún àwọn ọmọ Josẹfu, nígbà tí ó kọlu ilẹ̀ Ijipti. Mo gbọ́ ohùn kan tí n kò gbọ́ rí: tí ó wí pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi li o dasilẹ ni ẹrí fun Josefu, nigbati o là ilẹ Egipti ja; nibiti mo gbe gbọ́ ede ti kò ye mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fi múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìlànà fún Jósẹ́fù nígbà tí ó la ìlẹ̀ Éjíbítì já níbi tí a ti gbọ́ èdè tí kò yé wa.