Psalms 81:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Mo ti sọ àjàgà náà kalẹ̀ lọ́rùn rẹ; mo ti gba agbọ̀n ẹrù kúrò lọ́wọ́ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo gbé ejika rẹ̀ kuro ninu ẹrù: mo si gbà agbọn li ọwọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó wí pé, “Mo gbé àjàgà kúro ní èjìká yín, a tú ọwọ́ wọn sílẹ̀ kúrò nínú apẹ̀rẹ̀.