Psalms 82:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn kò ní ìmọ̀ tabi òye, wọ́n ń rìn kiri ninu òkùnkùn, títí gbogbo ìpìlẹ̀ ayé fi mì tìtì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn kò mọ̀, bẹ̃ni nwọn kò fẹ ki oye ki o ye wọn; nwọn nrìn li òkunkun; gbogbo ipilẹ aiye yẹ̀ ni ipò wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Wọn kò mọ̀ ohunkankan, wọn kò lóye ohunkankan. Wọn ń rìn kiri nínú òkùnkùn; a ni gbogbo ìpínlẹ̀ ayé.