Psalms 82:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo ní, “oriṣa ni yín, gbogbo yín ni ọmọ Ọ̀gá Ògo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi ti wipe, ọlọrun li ẹnyin; awọn ọmọ Ọga-ogo si ni gbogbo nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Mo wí pé, ‘Ẹyin ní “Ọlọ́run òrìṣà”; ẹ̀yin ní gbogbo ọmọ ọ̀gá ògo jùlọ.’