Psalms 82:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn sibẹsibẹ, ẹ óo kú bí eniyan, ẹ ó sùn bí èyíkéyìí ninu àwọn ìjòyè.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ẹnyin o kú bi enia, ẹnyin o si ṣubu bi ọkan ninu awọn ọmọ-alade.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ẹ̀yin o kú bí ènìyàn lásán; ẹ̀yin ó ṣubú bí ọ̀kan nínú ọmọ aládé.”