Psalms 82:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dìde, Ọlọrun, ṣe ìdájọ́ ayé, nítorí tìrẹ ni gbogbo orílẹ̀-èdè!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọlọrun, dide, ṣe idajọ aiye: nitori iwọ ni yio ni orilẹ-ède gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dìde Ọlọ́run ṣe ìdájọ́ ayé, nítorí gbogbo orílẹ̀ èdè ni ìní Rẹ.