Psalms 83:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣe àwọn ọlọ́lá wọn bí o ti ṣe Orebu ati Seebu; ṣe àwọn ìjòyè wọn bí o ti ṣe Seba ati Salumuna,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣe awọn ọlọla wọn bi Orebu ati bi Sebu: ani, gbogbo awọn ọmọ-alade wọn bi Seba ati Salmuna.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣe àwọn ọlọ́lá wọn bí Orébù àti Séébù, àwọn ọmọ aládé wọn bí Ṣébà àti Sálmúnà,