Psalms 83:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n pète àrékérekè sí àwọn eniyan rẹ; wọ́n sì gbìmọ̀ pọ̀ sí àwọn tí ó sá di ọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti gbimọ̀ arekereke si awọn enia rẹ, nwọn si ti gbèro si awọn ẹni-ìkọ̀kọ̀ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú àrékérekè ni wọn dìtẹ̀ sí àwọn ènìyàn Rẹ; wọn gbìmọ̀ lòdì sí àwọn tí ó fẹ.