Psalms 83:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ní, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á pa orílẹ̀-èdè wọn run; kí á má ranti orúkọ Israẹli mọ́!”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti wipe, Ẹ wá, ẹ jẹ ki a ke wọn kuro lati má wà li orilẹ-ède; ki orukọ Israeli ki o máṣe si ni iranti mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn wí pé, “wá,” ẹ jẹ́ kí a pa wọn run bí orílẹ̀ èdè, kí orúkọ Ísírẹ́lì ma bá a sí ní ìrántí mọ́.