Psalms 83:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
àwọn ará Gebali, àwọn ọmọ Amoni, ati àwọn ọmọ Amaleki, àwọn ará Filistia ati àwọn tí ń gbé Tire.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gebali, ati Ammoni, ati Amaleki: awọn ara Filistia pẹlu awọn ara Tire;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gébálì, Ámónì àti Ámálékì, Fílítísitíà, pẹ̀lú àwọn ènìyàn Tirẹ̀.