Psalms 83:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ará Asiria pàápàá ti dara pọ̀ mọ́ wọn; àwọn ni alátìlẹ́yìn àwọn ọmọ Lọti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Assuri pẹlu dapọ̀ mọ wọn: nwọn ràn awọn ọmọ Lotu lọwọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áṣurí pẹ̀lú tí darapọ̀ mọ́ wọn láti ràn àwọn ọmọ Lọ́ọ̀tì lọ́wọ́. Sela