Psalms 84:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ibùgbé rẹ lẹ́wà pupọ, OLUWA àwọn ọmọ ogun,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
AGỌ rẹ wọnni ti li ẹwà to, Oluwa awọn ọmọ-ogun!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ibùgbé Rẹ̀ ti lẹ́wà tó, OLÚWA Olódùmarè!