Psalms 84:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí OLUWA Ọlọrun ni oòrùn ati ààbò wa, òun níí ṣeni lóore, tíí dáni lọ́lá, nítorí OLUWA kò ní rowọ́ láti fún ẹni tí ọkàn rẹ̀ mọ́ ní ohun tí ó dára.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori Oluwa Ọlọrun li õrun ati asà: Oluwa yio fun ni li ore-ọfẹ ati ogo: kò si ohun rere ti yio fà sẹhin lọwọ awọn ti nrìn dede.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí OLÚWA Ọlọ́run jẹ́ òòrun àti àṣà; OLÚWA fúnni ní ojúrere àti ọlá; kò sí ohun rere kan tí yóò fàsẹ́yìn dádúró fún àwọn tí o rin ní aílábùkù.