Psalms 84:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ayọ̀ ń bẹ fún gbogbo àwọn tí ó fi ọ́ ṣe agbára wọn, tí ìrìn àjò sí Sioni jẹ wọ́n lógún.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibukún ni fun enia na, ipá ẹniti o wà ninu rẹ: li ọkàn ẹniti ọ̀na rẹ wà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbùkún ní fún àwọn tí agbára wọn wà nínú Rẹ àwọn tí wọ́n gbé ọkàn lé bíbẹ ibi mímọ́ wò.