Psalms 84:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn ó máa ní agbára kún agbára, títí wọn ó fi farahàn níwájú Ọlọrun ní Sioni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn nlọ lati ipá de ipá, ni Sioni ni awọn yọ niwaju Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n ń lọ láti ipa dé ipá títí tí ọ̀kọ̀kan fi farahàn níwájú Ọlọ́run ní Síónì.