bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Psalms 85:2
Psalms 85:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
O dárí àìdára àwọn eniyan rẹ jì wọ́n; o sì bo gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti dari aiṣedede awọn enia rẹ jì, iwọ ti bò gbogbo ẹ̀ṣẹ wọn mọlẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ dárí àìṣedédé àwọn ènìyàn Rẹ̀ jìn ìwọ sì bó ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀. Sela