Psalms 85:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣé o óo máa bínú sí wa títí lae ni? Ṣé ibinu rẹ yóo máa tẹ̀síwájú láti ìran dé ìran ni?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o binu si wa titi lai? iwọ o fà ibinu rẹ jade lati irandiran?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ yóò ha máa bínú sí wa títí láé? Ìwọ yóò ha mú ìbínú Rẹ pẹ́ yìí gbogbo ìran ká?