Psalms 86:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Fi àmì ojurere rẹ hàn mí, kí àwọn tí ó kórìíra mi lè rí i, kí ojú sì tì wọ́n; nítorí pé ìwọ, OLUWA, ni o ràn mí lọ́wọ́, tí o sì tù mí ninu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Fi àmi hàn mi fun rere; ki awọn ti o korira mi ki o le ri i, ki oju ki o le tì wọn, nitori iwọ, Oluwa, li o ti ràn mi lọwọ ti o si tù mi ninu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fi àmi hàn mí fun rere, kí àwọn tí ó kóriíra mi le rí, ki ojú le tì wọ́n, nítorí iwọ ni ó ti tù mi nínú.