Psalms 86:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí o dá ni yóo wá, OLUWA, wọn óo máa forí balẹ̀ níwájú rẹ: wọn óo sì máa yin orúkọ rẹ lógo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn orilẹ-ède ti iwọ da ni yio wá, nwọn o si sìn niwaju rẹ, Oluwa; nwọn o si ma fi ogo fun orukọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn orílẹ̀ èdè tí ìwọ dá yóò wá, láti wá jọ́sìn níwájú Rẹ, OLÚWA; wọn o mú ògo wà fún orúkọ Rẹ̀.