Psalms 87:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Tí mo bá ń ka àwọn ilẹ̀ tí ó mọ rírì mi, n óo dárúkọ Ijipti ati Babiloni, Filistia ati Tire, ati Etiopia. Wọn á máa wí pé, “Ní Jerusalẹmu ni wọ́n ti bí eléyìí.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o da orukọ Rahabu ati Babeli lãrin awọn ti o mọ̀ mi: kiyesi Filistia ati Tire, pẹlu Etiopia: a bi eleyi nibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èmi ó dárúkọ Rákábù àti Bábílónì láàrin àwọn tí ó jẹ́wọ́ mi: Fílístínì pẹ̀lú, àti Tirẹ, pẹ̀lú Kúṣì yóò sọ pé, èyí ni a bí ni Síónì.”