Psalms 87:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA yóo ṣírò rẹ̀ mọ́ wọn nígbà tí ó bá ń ṣe àkọsílẹ̀ àwọn eniyan rẹ̀ pé, “Ní Sioni ni a ti bí eléyìí.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa yio kà, nigbati o ba nkọ orukọ awọn enia, pe, a bi eleyi nibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA yóò kọ nínú àkọsílẹ̀ àwọn ènìyàn Rẹ̀: “Eléyìí ni a bí ní Síónì.”