Psalms 87:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn akọrin ati àwọn afunfèrè ati àwọn tí ń jó yóo máa sọ pé, “Ìwọ, Sioni, ni orísun gbogbo ire wa.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn olorin ati awọn ti nlu ohun-elo orin yio wipe: Gbogbo orisun mi mbẹ ninu rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti àwọn olorin àti àwọn ti ń lu ohun èlò orin yóò wí pé, “Gbogbo orísun mi ń bẹ nínú Rẹ.”