Psalms 88:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣé òkú ni o óo ṣe iṣẹ́ ìyanu hàn? Ṣé àwọn òkú lè dìde kí wọ́n máa yìn ọ́?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o fi iṣẹ iyanu rẹ hàn fun okú bi? awọn okú yio ha dide ki nwọn si ma yìn ọ bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ó fi iṣẹ́ ìyanu Rẹ hàn fún òkú? Àwọn òkú yóò ha dìde láti yín ọ́ bí?